“海南农信杯”2016第十一届环海南岛国...
Ilana yii j? if?w?si nipas? Wikimedia Foundation Board of Trustees. 百度 统筹设置党政机构。 O le ma yipo, par?, tabi foju par? nipas? aw?n o?i?? tabi o?i?? tabi aw?n ilana agbegbe ti eyikeyi i?? akan?e Wikimedia. |
ìdí tí afi ní àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí
Agbàgbó nínu ríró agbára fún gbogbo ènìyàn tí ó n kópa nínú àw?n i??? àti àw?n àyè wikimedia, láti lè dé bi ìran wa fún dídá irú ayé tí gbogbo ènìyàn lè pín nínu àw?n àkóp?? ìm?? àwa ?m? aráyé. Agbàgbó wípé àw?n olùkópa àj??ep?? wa yìí gb?d?? j?? onírúurú ènìyàn, àj??ep?? yìí sì gb?d?? fani m??'ra níw??n bí óti ?eése. Af?? kí àw?n ará àj??ep?? yìí máa wà ní dídára, p??lú ààbò t'ó pé'ye àti àyíká t'óní ìlera fún ?nik??ni tí ó bá f?? darap?? m?? w?n. A pinu láti ríi dájú pé ó wà báyìí, nípa fí'faram?? àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí yìí àti ìmúdójúìw??n ní gbà tí ó bá t??. P??lúp??lú, af?? dáàbò bo àw?n i??? Wikimedia kúrò l??w?? àw?n tí w??n bàáj?? tàbí díil??w??.
Ní ìbámu p??lú àfojúsùn Wikimedia, gbogbo ?ni tí o bá ti ń kópa nínú i??? Wikimedia yóò:
- sapá láti ?'??dá irú ayé tí gbogbo ènìyàn lè pín nínu àw?n àkóp?? ìm?? àwa ?m? aráyé
- kopa nínú awujo àgbáyé tí yíò jìnà sí ??tanú àti ìkóríra, p??lú
- sapá láti ríi dájú pé gbogbo àw?n i??? Wikimedia pé dé ojú ìw??n, ósì ?eé j??rìsí.
àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí (UCoC) yìí ?e àlàpín sí àw?n ìwà tí ó t??nà àti àw?n ìwà tí kò bójú mu. òfin yí de gbogbo ?nik??ni tí ó bá ti ní nkan ?e p??lú i??? àti àyeè àj??ep?? Wikimedia, yálà lórí ayélujára ni tabí ní ojúkojú. òfin yí ta bá àw?n akópa titun tàbí àw?n tí w??n ti n kópa tip??, àw?n alábòjútó àw?n i??? Wikimedia, àw?n olù???tò àp??j?, àw?n ?m? ?gb?? ìgbìm?? onígb??w?? àw?n ilé-i??? Wikimedia, àw?n ò?ì???, àti àw?n ?m? ?gb?? ìgbìm?? onígb??w?? Wikimedia Foundation. òfin yí ta bá àtèlé yìí:
- ìbá?ep?? àwùj? ìk??k??, ti gbangba, tàbí èyí tí ó wà ní agbede méjì
- àw?n ìjíròrò ti ìyapa àti àtìl??yìn fún ì???kan láàrin àw?n ará àj??ep?? Wikimedia
- àw?n ??r?? lórí ìdàgbàsókè ìm??-??r?? nà i???
- àw?n ??r?? tí ó dá lórí ?í?e àfikún àw?n àkòsíl??
- ìlànà bí àw?n ??ka a?oju Wikimedia ?e lè ?ojú w?n l??d?? àw?n alábàá?e w?n t'ìta
1 - ìfihàn
àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí ?'ètò ìpel??s?? iwà tí ó bójú mu fún àj??ep?? Wikimedia kárí àgbáyé. àw?n ará Wikimedia ?ì le fikún àlàkal?? yìí láti ?'??dá àlàkal?? tí yío j'?m?? ?akun à?à, àti ì?e tí ówà níl??, sùgb??n tí àlàkal?? Gbogboògbò sì gbod?? j?? ìpel??s?? fún.
àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí yìí de gbogbo àw?n ará Wikimedia ní bá'kàan láì y? ?nik??ni síl??. Tí'tàpá sí àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí yìí lè mú ìjìyà dání. àw?n ìjìyà yìí lè wá láti ?w?? àw?n ìgbìm?? amú????e Wikimedia tàbí/àti láti ?w?? Wikimedia Foundation, g??g?? bí olóun àw?n i??? àj??ep?? yìí
Gbogbo àw?n ará Wikimedia, yálà w??n ti p?? ni tàbí w??n ?????? forúk? síl?? ni, àw?n ìgbìm?? amú????e Wikimedia, àw?n ??ka tàbí àw?n ìgbìm?? onígb??w?? Wikimedia Foundation tàbí ò?ì???, ni won yóò ?e ìdúró fún ìwà w?n.
Nínú gbogbo àw?n i???, àyèè ati àpèj?? Wikimedia, ìwà ìb??w??-fún, ìm??t??, ìbá?ep?? tó l????rìn, ì???kan àti ìj?? a?ojú rere ni a ń retí l??w?? gbogbo àw?n olùkópa. àw?n ìwà w??nyí ni a gb??d?? ma gbóòórùn lará àw?n oní??? aláfikún àti olùkópa pátá nínú ìbá?ep?? w?n láàríin ara w?n, láì y? ?nik??ni síl?? nípa ?j??-orí, ìpèníjà ara, ì?esí, ìrísí, oríl??-èdè, ??sìn, ?l??yà-m??yà, ìd??y?síni, ipò-ayé, mím??r??'s?, ìbálòp?? ak? àti abo, ìják? tàbí ìjábo, ìm?? tàbí i??? ayé. A ò sì ní y? ?nik??ni síl?? nípa ìm?? tàbí i??? w?n nínú àj??ep?? Wikimedia.
<ìb??w?? fún ara ?ni>
A ní láti máa b??w?? fún ara wa g??g?? bí a ?e f?? kí w??n o b??w?? fún àwa náà ní àw?n àyíká Wikimedia, yálà lórí ??r? ayélujára ni tàbí ní ojúkojú. Agb??d?? maa b??w?? fún ?lòmíràn.x.
?Lará r?? tún ni:
- |Sí?e ìgbat?nirò. Fara bal?? gb?? ohun tí ?nik??ni nínú àw?n ak?gb?? r? tí w??n j?? onise Wikimedia ba f?? s? fún ?. Gbaradì láti lo ìm?? àti òyé r? lórí ohun tí o ti gb?? g??g?? bí oní??? Wikimedia.
- <J?? kí ?kàn r? ó m??, kí o sì s??r?? p??lú àròjinl??> àfíkun r? gb?d?? ?e àtún?e bá ìs?? tí ò nfikún. Fèsì sí ??r?? p??lú ??mí kan. Bí o bá ní ìyapa èrò lórí ??r?? kan, gbé ??r?? náà kal?? p??lú àròjinl??. Gbogbo ará Wikimedia gb?d?? ?e àtún?e p??lú ?kàn mím??, tí kòbá sí ??rí pé ?nìkejì j?? oníbàj??. P??lúp??lú, o kòsì gb?d?? s'??r?? ìpalára sí oníbàj?? tí o bábá w?n pàdé.
- B??w?? fún bí àw?n oní??? bá ?e pe orúk? tàbí ?àpèjúwe ara w?n. àw?n ènìyàn lè lo onírúurú ìlànà láti ?àpèjúwe ara w?n. G??g?? bí àp??r? ìb??w?? fún, lo ìlànà tí w??n bá fi pe ara won g??g?? bí w??n ?e lòó, nígbà tí o bá ń bá w?n s??r?? tàbí s??r?? nípa w?n, níw??nbí óti?éé?e. Bí àpeere:
- àw?n ?gb?? ??yà kan lè fi orúk? pàtàkì láti ?e àpèjúwè ara w?n, dípò orúk? tí àwùj? m?? w??n sí.
- àw?n ènìyàn kan lè lo àwon l??tà, ohùn, tàbí ??r?? láti inú èdè won tí yòò ?àjòjì sí ìw?;
- àw?n ènìyàn tí n?e ìbálòp?? ak? àti abo ??t??, léè lo ar??pò orúk? tó yàt??;
- àw?n ènìyàn tí w??n ní ìpèníjà ara kan tàbí òmíràn lè lo ohunkóhun láti fi jùwé ara w?n.
- Ní àw?n ìpàdé ojúkojú, a ó gbìyànjú láti fa gbogbo ènìyàn m??ra, a ó sì ri wípé a bu ??w?? fún àw?n àyòò, àlàà, ohun ìpalára, à?à, àti ìbéèrè oníkálukú.
<<ìwà-??t??, ìf?w??sow??p??, ì???kan àti ìj?? asojú rere>>
àw?nìwà tí à nretí nì yíí:
- <<ìwà-è?t??>> ni mím? ìwà, ??r?? àti ì?esí tí ó t?? láàrin àwùj?, p??lúp??lú àlejò.
- ìf?w??sow??p?? ni ìkúnra-?ni lápá tàbí à?à ìranra-?ni l??w?? tí ó y? láàrin àw?n alábà?is??p??.
- ì???kan àti ìj?? a?ojú rere ni mímú ojús? láti rí dájú wípé gbogbo àw?n is?? Wikimedìà n so èso, w??n dùn ún ?e, w??n sì n j?? àwùj? ààbò, àti fún ìdàgbàsókè àfojúsìn àj??ep?? Wikimedia.
Lará r?? náà tún ni:
- J?? At??nà àti Olùk??: Ran àw?n ?ni tí ó ?????? dara p?? l??w?? láti m??nà àti láti ní ìm?? kíkún lórí bí Wikimedia ?e ń ?i???.
- Fi ì?òkan hàn. Máa ran àw?n oní??? bíi tìr? l??w?? nígbà kúùgbà tí w??n bá nílò ìrànw?? r?, kí o sì s??r??-sókè fún w?n bí w??n bá n fi ??gbin kan w??n tí ó lòdì, g??g?? bí àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí.
- ?è'fihàn, kí o sì dúp?? fún i??? tí àw?n olùfarajìn n?e: Dúp?? fún ìrànw?? àti is?? w?n. ?è'rántí akitiyan w?n ní àw?n ibi tí ó ti y?.
3 - ìwà tí kò bójú mu
àlàkal?? Gbogboògbò fún ìhùwàsí yìí yóò ràn gbogbo àw?n ará wikimedia l??w?? láti lè ?e àdáyanrí àw?n ipò ìwà tí kò t??. àw?n ìwà w??nyí ni a lè pè ní ìwà tí kò t?? láàrín àwùj? àj??ep?? Wikimedia.
3.1 - ìy?l??nu
èyí j?? àw?n ìwà tí ó lè fa ìjayà tàbí ìbínú láti ??d?? ?lòmíìràn. A lè wo ìwà kan g??g?? bí ìwà ìy?l??nu nígbà tí ó bá ti k?já ohun tí ènìyàn lè gbà m??ra ní àwùj? àgbáyé ti onírúurú. ìwà ìy?l??nu má n ?ábà wáyé ní pasè ??dùn ?kàn, pàápàá sí àw?n tí ó bá wà ní ìkoríta ìpalára, nípa kíkàn sí ibi-is??, tàbí ??r?? àti ?bí, láti fa ìdàmú tàbí ìdójútì. Ní ìgbà míràn, àw?n ìwà tí kò ní ewu ní ìs??l?? kan, lè padà di ìwà ìy?l??nu, tí óbá wá ns?l?? léra léra. Ara àw?n ìwà ìy?l??nu ni:
- è?gbin tàbí ìw??sí: Ara èyí ni pípení lórúk? kórúk?, àbòsí, àti fífi èèbú ara búni. è?gbin tàbí ìw??sí ni bíbúni ní pas?? bí ?ni nà ?e n ronú, bí o ?e rí, ??yà àti ìran tí ó j??, irúf?? ??sìn tí ó n sìn, bí à?à àti i??? r?? ?e rí, ì?e ìbálòp?? r??, yálà ak? ni tàbí abo, ?j?? orí r?? ni, ?gb?? ò?èlú r?? ni tàbí àw?n nkan mííràn. Ní ìgbà mííràn, yí y??y?? ?ni, ìfini r??rìn tàbí ìfajúro síni léra léra sí ?lòmíràn lè túm?? sí ìw??sí tàbí ??gbin l'ápàap??, bí ì???l?? kan ti l?? ?e àìléwu.
- ìy?l??nu ìbá?ep??: ìfàm??ra fún ìbá?ep?? sí àw?n ènìyàn tí o m?? pé w??n f??, tàbí sí àw?n ènìyàn tí ó y? kí o m?? pé kò t?? nà, tàbí ní àw?n ipò tí kò ?éé ?e làti bèèrè fún ìgbàláyè w?n.
- ìhàl??: ìhàl?? ìwà-ipá m??ni ní ìpam?? tàbí ní gbangba, ìdójútì àìt??, ìbani lórúk? j?? àìt??, tàbí dídábàá làti p'ènìyàn l'??j?? nítorí kí o lè borí iyàn tàbí fi t'ipá j?? kí ènìyàn ?e ohun tí o f??.
- Gbígbìm?? ìkà fún àw?n ?lòmíràn: èyí lè j?? nípa gbígba ?lòmíràn ní ìyànjú láti ?e ìpalára tàbí gb??mí ara r??, p??lúp??lú gbígba ní'yànjú láti ?e ìkà tàbí ìjàmbá fún ??lòmíràn.
- à?írí títú: ?í?e ìfihàn àw?n à?írí ìk??k?? ?ni bíi: orúk?, ibi-is??, ibùgbé tàbí e-mail, lórí àj?s?p?? Wikimedia tàbí ibò míràn láì gba à?e l??w?? oní t??hún. èyí tún j?? ?í?e ìfihàn àw?n i??? tí oní??? n?e lórí Wikimedia sí'ta.
- ?í???'ni kiri: Títèlé ?nik??ni káàkiri gbogbo àw?n àj??e Wikimedia tí o sì n bu ?nu àt?? lu i??? onít??hún léraléra, p??lú èró ngbà láti mú w?n bínú, tàbí fa ìr??w??sì fún w?n. Tí i??? w?n bá n ní ì?òro léraléra l??yìn tí o ti gbìyànjú láti báw?n s??r?? àti k?? w?n, j?? kí àw?n ará àj??ep?? t'ókù yanjú ??r?? oní??? náà.
- ìtakoni kiri: Jíjáw? àw?n ìjíròrò tí óní??? wà káàkiri, l??nà tí kò t?? láti j?? kí w??n bínú.
3.2 - ìlòkulò agbára, à?fààní, tàbí òkìkí
ìlòkulò má n wáyé nígbàtí ènìyàn tí ó wà ní ipò agbára, à?fààní, tàbí òkìkí bá n hùwà àìb??w??, ìkà, àti/tàbí ipá sí àw?n ?lòmíràn. Ní àwùj? Wikimedia, ó lè wáyé ní ??nà ìtakùr??s? tàbí mímú làákàyé ?ni ?eré. A lè tún rí àw?n ìwà w??nyí g??g?? bí ??yà ìy?l??nu.
- ìlòkulò ip?? àw?n alábòjútó, olùdarí àti ò?ìs??: lílo ip?? à?e, ìm?? tàbí àw?n ohun èlò tí ó wà ní àr'??w?? tó àw?n alábòjútó, p??lú àw?n olùdarí àti ò?ìs?? Wikimedia Foundation tàbí ??ka Wikimedia, làti fi hal?? tàbí ?'??rùbà àw?n ?lòmíràn.
- ?í?i ipò àjùl? àti ìm?ni lò: Lílo ip?? tàbí orúk? ?ni láti fi hal?? m?? àw?n ?lòmíràn. à n re tí àw?n tí w??n ní ìrírí r?p?t?, tí w??n sì ti m? àw?n ara àj??ep?? yìí káà kiri, wípé kí w??n hùwà p??lú ìs??ra, nítorí àw?n ??r?? láti ?nu w?n lè dá wàhálà nlá síl??. àw?n ènìyàn p??lù à?e ní ànfààní pàtàkì tí ó n mú kí àw?n ènìyàn di ??r?? w?n mú, w?n kò si gb?d?? ?i ànfààní yìí lò nípa jíjà p??lú àw?n tí ó bá ?àìgba àw?n ìm??ràn w?n.
- Pípo làákàyè p??: Gbígbìyànjú láti j?? kí ènìyàn maa ?e iyèméjì ohun tí w??n n rí, èrò w?n, tàbí òye w?n, nítorí kí o bà le jàre iyàn tàbí fi t'ipá j?? kí w??n ?e ohun tí o f??.
3.3 - ìlòkulò tàbí ìbàj?? àw?n i??? Wikimedia
Mí m????m?? fi àw?n àfikún àbòsí, èké, ir?? tàbí àìt??nà, tàbí ?í?e ìdíl??w?? ì?èdá (àti/tàbí ìt??jú) àw?n àfikún míràn. Lára èyí ni:
- Yíy? àw?n àkòrí kùrò léraléra láì ?e ìjíròrò tót?? tàbí ?e àlàyé ??kúnr??r??
- Yíyípo àw?n àkòrí ní sísèntèlé láti j?? kí w??n ?àtìl?yìn fún àw?n ìtum?? tí kò y? (p??lú mím????m?? yí àw?n ìt??kasí àti àfíkún kúrò ní ??nà tí óti wà nl??)
- Sís'??r?? ìkóríra ní ??nàk?nà, tàbí lílo èdè ?l??yàm??yà fún èébú, ìdójútìni, tàbí rírú ìkóríra sí ?nìkan tàbí àw?n ?gb?? nítorí ìrí w?n tàbí ìgbàgb?? w?n
- Lílo àw?n àmì, àwòrán, ??ka, ohun ìdánim?? tàbí àw?n nkan míràn tí ó j?? ohun ìjayà tàbí ìpalára sí àw?n ?lòmíràn. Làra r?? ni dídarí àw?n ètò lórí àw?n àkórí tí ó n fa ìyapa.